YORUBA LANGUAGE SECOND TERM SS2 LESSON NOTE
ALL LESSON NOTES
| QUESTIONS AND ANSWERS
| JOBS
| TRAININGS FOR TEACHERS
| WORKSHEETS
YORUBA LANGUAGE SECOND TERM SS2 LESSON NOTE
SECOND TERM E-NOTE
SUBJECT; YORUBA. CLASS-; SS1
ILANA ISE OSOOSE FUN SAA KEJI
Ose kinni- Ede-Atunyewo awon isori oro
- oro aropo oruko
- oro aropo afarajoruko
- oro atokun
- oro asopo
- oro-ise
Asa- Oge sise
Litireso-Itupale asayan iwe litireso
Ose keji Ede- Awon isori gbolohun gege bi ihun won.
Asa- Oge sise
Aso wiwo laarin okunrin ati obinrin
Awon ayipada ti o de ba aso wiwo aye atijo ati ode-oni.
Litireso- Itupale asayan iwe litireso.
Ose keta Ede- Awon isori gbolohun gege bi ise won.
Asa- Asa ila kiko
- pataki ati iwulo ila.
Litireso- Itupale asayan iwe litireso.
Ose kerin Ede- Aroko Asapejuwe;ilana kiko aroko
- Awon ori-oro to je mo aroko asapejuwe.
Asa- Asa Igbeyawo Ni Ile Yoruba.
i. Awon igbese igbeyawo abinibi
ii. Awon ohun elo idana.
Litireso – Itupale asayan iwe litireso.
Ose karun-un Ede- Aayan Ogbufo; ilana sise aayan ogbufo.
Asa – Orisii igbeyawo ti o wa
i. igbeyawo nisu loka
gbigbe ese le iyawo
ana sise ni ile Yoruba.
Litireso- Itupale asayan iwe litireso.
Ose kefa Ede – Aayan Ogbufo; sise ogbufo ayoka ede Geesi si ede Yoruba.
Asa – Igbeyawo ode-oni-soosi, Yigi,Kootu.
- iyato ati ijora ti o wa ninu igbeyawo ode-oni ati atijo.
Litireso- itan olorogeere gege bi orisun itan isedale ati asa Yoruba
-itan isedale Yoruba
- itan awon eya Yoruba
ose keje- Ede- Onka Yoruba;onkaye lati ori ookan titi de Egbaa (1- 2000)
Asa- Oyun nini,itoju oyun,ibimo.
Igbagbo Yorubanipa agan,omo bibi ati abiku
Aajo lati tete ni oyun.
Eewo ati Oro idile.
Litireso - Itan oloro geere gege bi orisun itan ati asa Yoruba; Asa bi Yoruba se n sin oku sinu ile.
Ose kejo- Ede- Atunyewo eko lori eka ede Yoruba; Ijesa, Ekiti,Oyo.abbl.
- iwulo Yoruba Ajumolo
Fifi eka ede we Yoruba ajumolo
Asa- Isomoloruko Ni Ile Yoruba
i. Pataki siso omo loruko
ii. Ohun elo ati isomoloruko.
Litireso-Itupale asayan iwe litireso.
Ose kesan-an
EDE-Aroko asotan/ oniroyin.
Orisii ori-oro ti o je mo aroko oniroyin
Asa- Orisii oruko ti a le so omo
i. oruko amutorunwa
ii. abiso abbl
Litireso alohun oloro wuuru; Aalo orisirisi- apamo, apagbe,
iwulo aalo
awon ona ede ti o wa ninu aalo.
Ose kewaa- Ede- Isori oro-oruko
Oriki
Orisii
Ise ti oro-oruko n se ninu gbolohun.
Asa- Ipolowo oja; Iwulo ati pataki ipolowo oja.
Orisiirisii ona ipolowo oja ti abinibi-ikiri, ipate,ipolowo pelu ohun enu.
Litireso - Ewi alohun gege bi orisun itan isedale ati asa Yoruba; oriki orile,ijala abbl
Ose kokanla- Agbeyewo ise saa keji lapapo..
Ose kejila- Idanwo saa keji.
YORUBA LANGUAGE SECOND TERM SS2 LESSON NOTE
OSE KINNI
ORI-ORO-;ATUNYEWO AWON ISORI ORO
-Oro-oruko
ORO AROPO ORUKO.
- Oriki
- Abuda oro aropo oruko
- Ate oro aropo oruko
- Irisi oro aropo oruko.
AKOONU
Oro aropo oruko ni a maa n lo dipo oro-oruko ninu apola oruko.apeere
‘Bolu je akara.
‘O je e.’
‘ewure je agbado Bola’
‘ewure je agbado re.
Abuda oro aropo oruko.
1. Oro aropo oruko ni eto to n toka si iye bi eyo tabi opo.apeere
O lo [ eyo ni o ]
Won wa [ opo ni won]
1. oro aropo oruko ni eto to n toka si eni.apeere.
enikinni /eyi ni eni ti o n soro.
Enikeji / eyi ni eni ti a n soro sii.
Eniketa / eyi ni eni tabi ohun ti a n soro re.
Mo ko leta.
O ko leta
O ko leta.
3. Oro aropo oruko ni eto ipin si ipo.
IYE Eyo opo
Enikin-in-ni mo a
Enikeji o e
Eniketa o won.
4. A ko le fi oro-asopo so oro aropo oruko meji papo.apeere
mo ati o
wa ati won.
5. A ko le lo oro aropo oruko pelu da ati nko,ni,ko.apeere
mo n ko?
E da?
O ko?
6. A ko le lo eyan pelu oro aropo oruko.apeere
mo naa
e gan-an
IRISI ORO AROPO – ORUKO.
Ona meta Pataki ni a le gba lo oro aropo oruko ninu gbolohun.
- O le sise oluwa
- Abo
- Eyan ninu gbolohun.
Ipo oluwa; - oro aropo oruko maa n sise oluwa ninu gbolohun,
IYE EYO OPO.
Enikin-ni mo a
Enikeji o e
Eniketa o won
Apeere;- mo n jo
O n jo
Won n jo
E n jo
A n jo.
Ipo abo : - oro aropo oruko maa n sise abo bakan naa ninu gbolohun.
Iye Eyo Opo.
Enikin-in mi wa
Enikeji o/e yin
Eniketa faweli won
Oro-ise gun
YORUBA LANGUAGE SECOND TERM SS2 LESSON NOTE
Baba na mi.
Bolu n pe o/e
Oluko pe e.
Oba ri wa.
Ipo eyan : -oro aropo oruko maa n ni ipo eyan ninu gbolohun.
IYE EYO OPO.
Enikin-ni mi wa
Enikeji re/e yin
Eniketa re/e won.
Apeere; -
Aja mi
Aja re
Aja re
Ile wa
Aso yin
Aja won.
IGBELEWON.
1. Kin ni oro aropo oruko?
2. salaye awon oro aropo oruko pelu apeere.
ORO AROPO AFARAJORUKO.
- Oriki
- Abuda oro aropo afarajoruko
- Irisi oro aropo afarajoruko.
- AKOONU : -
Oro aropo-afarajoruko ni isesi to farajo ti oro-oruko sugbon o mu eto iye ati eni lara abuda oro aropo oruko.Awon oro aropo afarajoruko ni wonyii; - emi,iwo,oun,awa,eyin,awon.fun apeere.
Emi ko ri Bola.
Ile awa dun.
Abuda oro aropo afarajoruko.
i. Oro aropo afarajoruko ni eto iye ati eni.
Ate oro aropo afarajoruko.
IYE EYO OPO.
Enikin-ni emi awa
Enikeji iwo eyin
Eniketa oun awon.
Fun apeere : - iwo ni won ran
Awa naa n bo.
ii. A le lo oro asopo lati so oro aropo afarajoruko meji papo.apeere.
emi ati iwo.
Awa ati eyin.
iii. Oro aropo afarajoruko le jeyo pelu awon wunren bii da,nko,ko.Fun apeere
iwo n ko?
Oun da?
Eyin ko.
iv. Silebu meji ni oro aropo afarajoruko maa n ni.apeere.
emi – e /mi.
iwo – I /wo.
v. Oro aropo afarajoruko le gba eyan.Apeere
emi naa wa.
Awon gan-an wa.
i. A le gbe oro –aropo afarajoruko saaju wunren akiyesi alatenumo ‘ni’ fun apeere
1. Eyin ni oga n pe.
2. emi ni mo ra iwe naa.
IRISI ORO AROPO AFARAJORUKO.
Ise oluwa ni oro aropo afarajoruko maa n se ninu gbolohun.ap.
Emi naa mu osan.
Oun ni won n bawi.
LITIRESO.
Kika iwe litireso.
ORO APONLE
YORUBA LANGUAGE SECOND TERM SS2 LESSON NOTE
AKOONU
Oro-aponle je oro ti o maa n pon oro-ise ninu gbolohun, o ma n se afikun itumo fun apola-ise, ti yoo si je ki itumo re si tubo ye ni yekeyeke.
Tobi jeun die
Bolu n rin kanmokanmo bo
Ninu apola-ise ni oro-aponle ti maa n jeyo ninu gbolohun
Oro-ise ni oro-aponle maa n pon ninu gbolohun oro-aponle maa n se afikun ituom fun oro-ise.
Tade dide fuu
Igi naa ga fiofio
Irufe oro-aponle inu ede Yoruba orisii meji ni oro-aponle, awon naa ni:-
Awon oro-aponle aiseda
Awon oro-aponle aseda
Oro aponle aiseda ni oro-aponle ti a ko seda, iru oro yii kii ni ju silebu kan tabi meji lo. A won ni fio, kia, gan-an logan
O lo logan
Ile naa ga fio
YORUBA LANGUAGE SECOND TERM SS2 LESSON NOTE
DO YOU WANT FULL NOTE JUST FOR 500 NAIRA ONLY,
PLEASE CLICK ON THE LINK BELOW
CLICK HERE TO CHAT WITH US ON WHATSAPP
+2349123700105
Comments
Post a Comment